Soapy lyrics
 by Naira Marley
		
[Intro]
Ó t'esè lé èfó
Yahoo ni babaláwo (Yawo ni babaláwo)
Olè l'everybody
Eni ilè mó bá ṣá ni bàráwò
(Bàráwò, bàráwò, bàráwò)
Mó bá ṣá ni bàráwò
[Verse 1]
Ó t'esè lé èfó (Ó t'esè lé èfó)
Yawo ni babaláwo (Yawo ni babaláwo)
Olè l'everybody
Eni ilè mó bá ṣá ni bàráwò
Ó fé ṣè'kà fún mi (Ófé ṣè'kà fún mi)
Mi ò l'ógùn mo nà Kùránì (Mo nà Kùránì)
Mo dè ń ṣ'àdúrà mi
Bà n sé ń ṣ'àdúrà mi, Allah ń gbà'dúrà mi (Allah ń gbà'dúrà mi)
A ti lo a ti dé (A ti lo a ti dé)
Eni orà yo ó dilé (Eni orà yo ó dilé)
Enà ba lo l'ó ba dé
Ìgbà tà n padà dé ń'ṣe l'ón dé mi l'ádé (Ń'ṣe l'ón dé mi l'ádé)
K'ádé k'ó pé l'órà (K'ádé k'ó pé l'órÃ)
Kà bàtà k'ó pé l'ésè (Kà bàtà k'ó pé l'ésè)
K'àwon òtá mi kán l'ésè
K'àwon [?] [?] kà wón kán l'ésè
[Bridge]
Inside life, l'oó ti rà Five Alive (L'oó ti rà Five Alive)
Inside life, l'oó ti rà Deeper Life (L'oó ti rà Deeper Life)
Inside life àwon kan ń jè'yà, àwon kan ń chop life (Inside life)
Inside life àwon kan ń ṣ'épè, àwon kan ń j'èwà
[Chorus]
Jó soapy (Soapy)
KirÃkirì Å„ jó soapy (KirÃkirì Å„ jó soapy)
Jó soapy (Soapy)
Ìkòyà prison ń jó soapy (Ìkòyà prison ń jó soapy)
Jó soapy
NÃnú cell EFCC wón Å„ jó soapy (Wón Å„ jó soapy)
Jó soapy
T'ó ò bá nÃ'yàwó Å„'lé k'o jó soapy (Soapy)
Soapy (Soapy)
Bròdá yì ń jó soapy (Bròdá yì ń jó soapy)
Soapy (Soapy)
Àbà èyin náà soapy (Àbà èyin náà soapy)
Soapy (Soapy)
Single father ń jó soapy (Single father ń jó soapy)
Soapy
Má lo lo Omo t'o bá lo ń soapy (Soapy)
[Verse 2]
Ṣ'o d'ówó mò (Ṣ'o d'ówó mò)
Owá so pé òmo Naira (Owá so pé òmo Naira)
Ówúwo l'ówó, ìwo ṣáà ṣe sà Naira (Ìwo ṣáà ṣe sà Naira)
Ajá fé dè'nà d'ekùn
Kékeré ekùn ò mà ń ṣ'egbé ajá (Kò ń s'egbé ajá)
Wón ń bé ni, má fòó, àwon náà ò fé wàhálà (Àwon náà ò fé wàhálà)
I just want make mama proud (I just want make mama proud)
They want to make mama cry (They want to make mama cry)
Mama, you gonna cry no more
T'e bá sun'kún gan, e ó so'kún ayò (E ó so'kún ayò)
Tà n bá ń jó k'e bá n yò (K'e bá n yò)
K'órò mà já s'áyò (K'órò mà já s'áyò)
Inside life (Inside life)
Kú àwon 'cause it's my life (Kú'òn'bè!)