Eyé Àdabá lyrics

by

Aṣa


Oju mo ti mo
Oju mo ti mo mi
Ni le yi o o
Oju mo ti mo - mo ri re o

Eye adaba
Eye adaba
Eye adaba ti n fo lo ke lo ke
Wa ba le mi o o
Oju mo ti mo mo ri re o

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z #
Copyright © 2012 - 2021 BeeLyrics.Net